HYMN 852

8.7.8.71. “GBAT' agbara Olorun de 

   Li ojo Pentikosti 

  Sa if’oju s’ona pari 

  ‘Tori won ri Emi gba.

Egbe: Ran agbara, Oluwa 

     Ran agbara, Oluwa 

     Ran agbara, Oluwa

     Ki O si baptis’wa.


2. Ela ahon ina ba le won 

   Won si wasu oro na 

   Opolopo eeya gbagbo 

  Won yipada s'Olorun.


3. A nw‘ona fun Emi Mimo 

  Gbogbo wa f’ohun sokan 

  Mu ‘leri na se, Oluwa

  Ti a se nin’oro Re.


4. Jo fi agbara Re kun wa 

   Fun wa ni ‘bukun ta nfe 

   Fi ogo Re kun okan wa 

   Ba ti nfi ‘gbagbo bebe. Amin

English »

Update Hymn