HYMN 854

881071. lSEGUN wa li okan mi 

   Nitori Emi ngbe 'nu mi 

   Jeki igbi idanwo de

   Jesu mura lati gba mi.

Egbe: Isegun! Isegun! isegun l‘okan mi

     Mo ni isegun nla ‘tori Jesu 

     gb‘okan mi

     Isegun! lsegun! bi odo sisan 

     Mo nsegun nla ninu eje Jesu.


2. Bi ‘ja tile le to si pe

   Bi esu tile b‘okan mi ja 

   Sibe, mo je alagbara 

   L’agbara Jesu, ngo segun.

Egbe: Isegun! Isegun!...


3. Mo ni ‘segun lori ese 

   Mo ni segun lori ‘boji 

   Ani iku ko ni ‘pa mo

   Aleluya! emi ti la.

Egbe: Isegun! Isegun! isegun l‘okan mi

     Mo ni isegun nla ‘tori Jesu 

     gb‘okan mi

     Isegun! lsegun! bi odo sisan 

     Mo nsegun nla ninu eje Jesu. Amin

English »

Update Hymn