HYMN 855

8s 6s1. EMI at’ara ile mi

   Yoo ma sin Oluwa wa 

   Sugbon emi papa

   Yon f’iwa at’oro han 

  Pe mo mo Oluwa t’orun 

  Mo nf‘okan toto sin.


2. Em’o f‘apere ‘re le le

   Un o mu idena na kuro

   Lodo om'odo mi

   Un o f'ise won han ni iwa mi 

   Sibe n‘nu 'se mi ki nsi ni

   Ola na ti ife.


3. Emi ki y'o soro gb’ipe 

   Emi y'o pe tu ninu 

   Om‘eyin Olorun

   Mo si fe je eni mimo 

   Ki nsi fa gbogbo ile mi 

   S'oju ona orun.


4. Jesu, b‘o ba da ‘na fe na 

   Ohun elo t'lwo fe lo 

   Gba s’owo ara Re

   Sise ife rere n'nu mi

   Ki nfi b'onigbagbo toto 

   Ti ngbe l’aye han won.


5. Fun mi l'or’ofe toto 

   Nje! Emi de lati jeri 

   Yanu oruko Re

  Ti o gba mi lowo egbe 

  Ire eyi t’a mo l'okan 

  Ti gbogb’ahon le so.


6. Emi t'o bo lowo ese

   Mo wa lati gba le mi la

   Ki nwasu dariji

   F‘omo, f‘aya f’omo ‘do mi 

   Lati mu won to ‘na rere 

   Lo si orun mimo. Amin

English »

Update Hymn