HYMN 858

7.7.7.7.D1. MO mbo nib agbelebu
 
   Emi abosi julo

   Mo ka gbogbo nkan s‘ofo

   Lati ri gbala kikun.

Egbe: Mo gbekele O, Jesu

     Odagutan Kalfari

     Mo fi 'rele teriba

     Gba mi, Jesu loni yi.


2. Mo gbekele 'leri Re 

   At'agbara eje ni

   Mo pon ara mi l'oju 

   Mo ru agbelebu Re.

Egbe: Mo gbekele O...


3.  Jesu fi ayo kun mi 

   O si so mi di pipe

   Mo ni ilera pipe

   Ogo ni f‘od'agutan.

Egbe: Mo gbekele O, Jesu

     Odagutan Kalfari

     Mo fi 'rele teriba

     Gba mi, Jesu loni yi. Amin

English »

Update Hymn