HYMN 88

S.S. & S. 209 (FE 105)
"F’ibukun fun Oluwa, iwo okan
mi" - Ps. 104:11. A YIN Oba Ogo, On li Olorun

   E yin fun 'se yanu ti O se fun wa

   Fun siso t'o nso wa ni ojo gbogbo

   Fun owo ina ati awosanma.

Egbe: Enyin Angeli didan

      fi Harpu wura yin

      Enyin Ogun Orun t'e nri oju Re

      Yika gbogbo aiye titi?

      Lai n’ise Re y’o ma yin

      Fi ibukun f ’OIuwa iwo okan mi.


2. E yin fun igbala to fun wa l’ofe

   E yin fun Orisun to le we wa mo

   E yin fun ore ati itoju Re,

   E yin pelu pe O ngbo adura wa.

Egbe: Enyin Angeli...


3. E yin fun idanwo, ti o nran si wa

   Lati fi s'okunfa wa s‘odo ‘ra Re

   E yin fun igbagbo lati ma segun

   E yin fun ‘leri ilu orun rere.

Egbe: Enyin Angeli... Amin

English »

Update Hymn