HYMN 90

(FE 107)
"E fi ope fun Oluwa” - Ps. 136:11. AWA dupe, awa t'ope da,

   T'o ti pa agbara ina ileru

Egbe: Ogo ni fun, Ogo ni fun

      Ogo ni f'Oruko Re.


2. Aje, oso at’alawirin, sonponna,

   Irun-Mole ti di ‘temole.

Egbe: Ogo ni fun...


3. Awa omo egbe Serafu,

   E mura ka si le te esu mole.

Egbe: Ogo ni fun...


4. Enit' o ro p‘on ti duro

   K‘o sora ki o ma ba subu lule.

Egbe: Ogo ni fun...


5. Orin Halleluyah l'ao ko

   ‘Gbati gbogbo idanwo ba koja lo.

Egbe: Ogo ni fun...


6. E f'ogo fun Baba wa l'oke

   Ka si f'ogo f‘Omo Re l'orun.

Egbe: Ogo ni fun...


7. K'a f‘ogo fun Emi Mimo

   Metalokan si l'ope ye fun.

Egbe: Ogo ni fun...


8. Ogo ni fun, Ogo ni fun

   Ogo ni f’Oruko Re.

Egbe: Ogo ni fun... Amin

English »

Update Hymn