HYMN 114

H.C. 567. t.H.C. 520 C.M (FE)
"Emi o ma fi ibukun fun Oluwa
nigbagbogbo" - Ps. 34:11. N‘NU gbogbo ayida aiye

   Ayo on wahala

   lyin Olorun ni y'o ma 

   Wa l'enu mi titi.


2. Em‘o yangan ti segun Re 

   Tit'awon t'eru npa

   Y‘o fi mi se awokose

   Ti banuje y‘o tan.


3. Gbe Oluwa ga pelu mi,

   Ba mi gb'Oko Re ga

   N'nu wahala. ‘gba mo kepe 

   O si yo mi kuro.


4. Ogun Olorun wa yika 

   lbugbe oloto;

   Eniti o ba gbekele 

   Yio si ri ‘gbala.


5. Sa dan ife Re wo lekan 

   Gbana ‘wo o mo pe 

   Awon t‘o di oto Re mu 

   Nikan l’eni 'bukun.


6. E beru Re, enyin mimo, 

   Eru miran ko si,

   Sa je ki 'sin Re j‘ayo nyin, 

   On y'o ma toju nyin. Amin
 

English »

Update Hymn