HYMN 136

(FE 153)
Tune: F’eru re f’a fefe S.M.1. F'IBUKUN f’Oluwa!

   K’okan at’inu mi,

   Pel'ahon mi yin Oko Re, 

   Fun gbogbo ore Re.


2. F’ibukun f’Oluwa 

   Okan mi ma gbagbe 

   Lati s’ope, Iati f'iyin 

   Fun opo anu Re.


3. O f'ese re ji O 

   O mu ‘rora re lo

   O wo gbogbo arun re san, 

   O so o d’atunbi.


4. O f' onje f ‘alaini 

   lsimi f’ojiya;

   Y'o se ‘dajo agberaga 

   Y’o gbeja alaise.


5. O f‘ise 'yanu Re,

   Han, lat’ owo Mose 

   Sugbon oto at’ore Re

   L'o fi ran Omo Re. Amin

English »

Update Hymn