HYMN 14

C.M.S 140, t.HC 120, D. 8s 7s (FE 31)
"Eniti npa o mo, ki yioo togbe" - Ps. 121:3


1. lFE Re da wa wa si loni,

L'are a si dubule;

Ma so wa ni dake oru 

K'ota ma yo wa lenu;

Jesu, se Olutoju wa,

lwo l'o dun gbekele. 

Egbe: Hulleluyah, Halleluyah 

      Ni won nko t'osan t'oru 

      Nibi t'Olugbala ngbe

      Ni won nko t'osan t'orun


2. Ero at‘alejo t‘aiye

A ngb‘arin awon ota!

Yo wa, at‘ile wa l‘ewu 

L’apa Re ni ka sun si; 

N'ijo iyonu aiye pin, 

Ka le simi l'odo Re. 

Egbe: Halleluyah, Halleluyah... Amin

English »

Update Hymn