HYMN 152

CM.147, t.H.C 400 C.M. (FE 170) 
"Woli nIa dide li arin wa” - Luku 7:161. 'WO, owon Olurapada 

   A fe ma gburo Re

   Ko s'orin bi oruko Re, 

   T'o le dun t'abo re.


2. A! a ba le ma gbohun Re, 

   L’anu soro si wa,

   Nin’ Alufa wa l’a o yo 

   Melkisedek giga.


3. Jesu ni y’o se orin wa, 

   Nigbat’ a wa l‘aiye

   A o korin ife Jesu 

  'Gba nkan gbogbo baje


4. Nigba 'ba yo soke lohun

   Pelu 'jo, eni Re

   'Gbana a o korin kikan

   Kristi'mi y'o j'orin wa. Amin

English »

Update Hymn