HYMN 17

C.M.S 19, H.C 35, S.M. (FE 34)
"Nisisiyi ni igbala wa sunmole ju 
lgbati awa ti gbagbo lo" - Rom. 13:11


1. ERO di dun kan nso

   S'okan mi fi ri fi ri, 

   Mo sunmo ‘le mi lo ni 

   Ju bi mo ti sunmo ri.


2. Mo sunmo ‘te nla ni, 

   Mo sunm‘okan Kristi 

   Mo sumo ‘le Baba 

   Nibiti 'bugbe pupo wa.


3. Mo sunmo 'te nla ni, 

   T'a so e ru kale

   T‘a gb'agbele bu si le 

   T'a si be re gb'ade.


4. Lagbedemeji eyi,

   Ni ‘san‐omi dudu

   Ti a o la koja dandan 

   K‘a to de ‘mole na.


5. Jesu, jo se mi pe

   So ‘gba gbo mi di lile 

   Je ki n mo p'O sunmo mi 

   Leti bebe iku.


6. Ki nmo p'O sunmo mi

   Gba mba njin si koto;

   O le je pe mo nsumole, 

   Sunmo ju bi mo ti ro. Amin

English »

Update Hymn