HYMN 183

CM.S 50 O. t H. C. 141 7s (FE 201)
"Idajo nla" - Juda 61. OJO 'dajo on 'binu

   Ojo ti Jesu pa ni 

   Gbobgo a so n'jo na!


2. Kikan n'ipe o ma dun 

   Isa oku yio si,

   Gbogbo oku y'o dide.


3. Iku papa y'o diji

   Eda gbogbo y'o dide

   Lati jipe Olorun.


4. A o si Iwe sile

   A o si ka ninu re

  Fun 'dajo t'o ku t'aye.


5. Onidajo Ododo

   Jo w'ese mi gbogbo nu 

   K'ojo siro na to de. Amin 
 

English »

Update Hymn