HYMN 192

C.M. 56 t.H.C 154 C.M. (FE 210) 
"E pese okan nyin sile"
- 1 Sam. 7:31. JESU t'o ga julo lorun 

   lpa Re l'od’aiye

   ‘Wo f‘ogo nlanla Re sile 

   Lati gba aiye la.


2. O w' aiye airo irele 

   Ni ara osi mi wa 

   Nitori k‘okan t‘o sile 

   Be t’ipase Re la.


3. Wiwa Re ya Angeli l‘enu 

   Ife t‘o tobi ni

   Enia l'anfani iye

   Angeli se, ko ni.


4. Nje araiye yo, sa nyin de, 

   E ho iho ayo

   lgbala mbo fun elese 

   Jesu Olorun ni.


5. Oluwa, jo ki bibo Re 

   Nigba erinkeji

   Je ohun ti a nduro de, 

   K’ o le ba wa Layo. Amin

English »

Update Hymn