HYMN 193

C.M.S 65 t. H.C 14 L.M (FE 211)
"Awa mo pe Omo Olorun de" 
- I John 5:201. ONIDAJO na de, O de! 

   Beni ‘pe keje ti ndun nwi 

   Manamana nko, ara nsan 

   Onigbagbo y’o ti yo to!


2. A ngbo, Angel orun nwipe 

   Jesu Oluwa wa d‘ade 

   Ore’Ofe l’On fi damure

   Ogo l‘On fi s'oso boju.


3. ‘Wo sokale l’or‘ite Re

   O gba ijoba fun ‘ra Re

   Ijoba gbogbo gba Tire 

   Nwon gba b’Oluwa t’o segun.


4. Gbogbo ara orun, e ho 

   At’ enia Oluwa wa,

   Oga ogo t’o gba ola

   Yio joba lai ati lai. Amin

English »

Update Hymn