HYMN 229

O.t.S. 57. 8s. 7s (FE 249)
"Nwon igbati aiye yio wa, igba orun 
on ojo ati osan ati oru ki yio 
dekun." - Gen. 8:22
Tune: Okan mi yin Oba orun1. OLOWA alafia wa, 

   L’opase t'odun yipo 

   Awa omo Re wa dupe 

   F'odun titun t’a bere 

   Yin Oluwa! Yin Oluwn 

   Oba nla t'O da wa si.


2. A dupe fun ipamo wa 

   Ni odun ti o koja

   A mbebe iranlowo Re, 

  Fun gbogbo wa lodun yi 

  Jek’ljo wa, jek’ljo wa 

  Ma dagba ninu Kristi.


3. K’agba k'o mura lati sin 

   Lokan kan ni odun yi 

   K'awon omode k‘o mura

   Lati saferi Jesu 

   K’alafia, k’alafia 

   K’o se ade odun yi.


4. K‘Emi Mimo lat’ oke wa 

   Ba le wa ni odun yi

   Ki Alufa at’Oluko 

   Pelu gbogbo Ijo wa

   Mura giri, Mura giri 

   Lati Josin f'Oluwa. Amin

English »

Update Hymn