HYMN 234

K. 194 t.H.C 156 DIM (FE 254)
"O si pe oruko re ni Ebeneseri wipe: titi de
ihin li Oluwa ran wa Iowa” - 1 Sam. 7:121. OLUWA ati ’gbala wa 

   Amona at’agbara wa 

   L'o ko wa jo l'ale oni

   Jek’ a gbe Ebeneseri ro 

   Odun t’a ti le koja

   Ni On f’ore Re de lade 

   Otun l’anu Re l’Owuro 

   Nje ki ope wa ma po si!


2. Jesus t’o joko lor' ite

   L’a fi Halleluyah wa fun 

   Nitori e nikansoso

   L'a da wa si lati korin

   Ran wa lowo lati kanu 

   Ese odun t’o ti koja

   Fun ni k‘a lo eyi ti mbo

   S'iyin Re ju odun t’o lo. Amin

English »

Update Hymn