HYMN 237

CMS. 141 7.7.7 (FE 257)
"Jeki nwon wipe, Da awon enia Re
si, Oluwa, ma si se fi ini Re fun 
egan” - Joeli 2:171. JESU, l‘ojo anu yi 

   Ki akoko to koja 

   A wole ni ekun wa.


2. Oluwa, m‘ekun gbon wa 

   Fi eru kun aiya wa

   Ki ojo iku to de.


3. Tu Emi Re s'okan wa 

   L’enu ona Re la nke 

   K'ilekun anu to se.


4. Tori waiya-ija Re 

   Tori ogun-eje Re 

   Tori iku Re fun wa.


5. Tor‘ekun kikoro Re 

   Lori Jerusalemu 

   Ma je ka gan ife Re.


6. lwo Onidajo wa 

   Ghat'oju wa ba ri O 

   Fun wa n’ipo lodo re.


7. lfe Re l'a simi le 

   N'ile wa l'oke l‘a o mo 

   B'ife na ti tobi to. Amin

English »

Update Hymn