HYMN 238

C.M.S.152 t.H.C. 27
tabi A. &. M 101 S.M (FE 258)
"Emi korira ara mi, mo si ronupiwada
se toto ati ninu ekura ati eru" - Jobu 42:61. ALAIMO ni emi 

  Olorun Oluwa!

  Emi ha gbodo sunmo O, 

  T'emi t'eru ese?


2. Eru ese yi npa

   Okan buburu mi 

   Yio ha si ti buru to 

   L'oju Re mimo ni!


3. Emi o ha si ku

   Ni alainireti? 

   Mo r'ayo ninu iku Re 

   Fun otosi b‘emi.


4. Eje ni ti o ta

   T’ise or‘ofe Re

   Le w'elese, t'o buru ju 

   Le m‘okan lile ro.


5. Mo wole l'ese Re

   Jo k‘ O dariji mi 

   Nihin l’emi o wa titi 

   Wo o wipe "Dide." Amin

English »

Update Hymn