HYMN 239

C.M.S. 146 t. H.C 247 DSM (FE 259)
"E mu gbogbo ihamora Olorun wo" 
- Efe. 6:111. JESU, gbara mi 

   Iwo l’aniyan mi

   Emi fi igbagbo woke 

   Iwo I’o ngbadura 

   Je ki nduro de O

   Ki nle se ife Re

   Ki iwo Olodumare 

   K'o so mi di otun.


2. Fun mi l’okan rele 

   Ti ‘ma se ara re

   Ti ntemole, ti ko nani 

   lkekun Satani

   Okan t’ara re mo 

   lrora at‘ise

   T'o nfi suru at’igboiya 

   Ru agbelebu re.


3. Funmi l‘eru orun

   Oju to mu hanhan

   T'yo wo O ngbe ese sunmole 

   K'ori b’Esu ti nsa

   Fun mi ni emi ni

   T'O ti pese tele

   Emi t'o nduro gangan lai 

   T'o nf‘ adura sona.


4. Mo gbekele’oro Re, 

   Wo l’o leri fun mi 

   lranwo at’igbala mi

   Y'o t‘odo Re wa Se 

   Sa je ki nle duro

   K’ireti mi ma ye 

   Tit'lwo o fi mo‘kan mi 

   Wo ‘nu isimi Re. Amin

English »

Update Hymn