HYMN 247

C.M.S 150 t.H.C 164
tabi H.C 140 C.M (FE 267) 
"Enyin pelu nfe lo bi?" - John 6:671. NIGBA nwon kehin si Sion, 

   A! opo n'iye nwon

   Mo se b'Olugbala wipe

   Wo fe ko mi pelu?


2. T’emi t’okan b'iru eyi

   A fi b'O di mi mu

   Nko le se ki nma fa s’ehin 

   K’emi si dabi won.


3. Mo mo, lwo I’o l’agbara 

   Lati gba otosi

   Odo tani emi opo lo

   Bi mo kehin si O?


4. O da mi loju papa pe 

   lwo ni Kristi na! 

   Enit' o ni emi iye 

   Nipa ti eje Re.


5. Ohun Re f ’isimi fun mi 

   O si l‘eru mi lo

   lfe Re lo le mu mi yo 

   O si to f’okan mi.


6. Bi ‘bere yi ti dun mi to

   ‘Pe emi o lo bi?

   Oluwa, ni ‘gbekele Re

   Mo dahun pe “Beko.” Amin

English »

Update Hymn