HYMN 249

C.M.S.154 H.C 323, C.M (FE 269)
“Awa ko ni Olori Alufa ti o se
alaimo edun ailera wa" - Heb. 4:151. A F‘AYO ri ore-ofe 

   T'Alufa giga wa,

   Okan Re kun fun iyonu 

   lnu Re nyo fun ‘fe.


2. Tinutinu l'o ndaro we 

   O mo ailera wa

   O mo bi idanwo ti ri 

   Nitori O ti ri.


3. On paapo l‘ojo aiye Re 

   O sokun kikoro

   O mba olukuluku pin 

   Ninu iya ti nje.


4. Je ki a f’igbagbo ‘rele 

   W’anu at’ipa Re

   Awa o si ri igbala 

   L'akoko iyonu. Amin

English »

Update Hymn