HYMN 262

C.M.S.188 H.C. 173 L.M (FE 282)
“E tetilele, ki e si wa si odo mi, e
gbo, okan nyin o si ye" - Isa. 55:31. OLORUN, Baba mi, Wo npe

   Asako omo Re mora?

   Iwo o ha dariji mi?

   Mo de, mo de, jo gba mi la.


2. A! Jesu, Iwo nrekoja
  
   Pelu ore at‘agbara?

   'Wo ko ha ngbo igbe mi?

   Mo de, mo de, sanu fun mi.


3. A! Emi Mimo Iwo ni?

  Ore ti mo ti sati pe!

  Wo ha mbebe fun mi sibe?

  Mo de, mo de, m'ailera le.


4. Mo de, Oluwa, ife Re

   Ni o nro mi t'o si nfa mi

  Mo wole lese re, ki nmo

  B'o ti dun lati je Tire. Amin

English »

Update Hymn