HYMN 265

H.C. 172 t.S 56 8s 7s. 3 (FE285)
"Ojo ibukun o si ro” - Esek. 34:261. Oluwa mo gbo pe, Iwo 

   Nro ojo ‘bukun kiri 

   ltunu fun okan are

   Ro ojo na sori mi.

Egbe: An emi, an’emi 

      Ro ojo na sori mi.


2. Ma koja Baba Olore 

   Bi ese mi tile po

   Wo le fi mi sile sugbon 

   Je k’anu Re ba le mi. 

Egbe: An emi, an’emi...


3. Ma koja mi, Olugbala 

   Je k'emi le ro mo o 

   Emi nwa oju rere Re 

   Pe mi mo awon t’o npe. 

Egbe: An emi, an’emi...


4. Mo koja mi, Emi Mimo 

   Wo le la ‘ju afoju

   Eleri itoye Jesu

   Soro as na si mi.

Egbe: An emi, an’emi...


5. Mo ti sun fonfon nin’ese 

   Mo bi O ninu koja

   Aiye ti de okan mi jo

  Tu mi k'o dafiji mi. 

Egbe: An emi, an’emi...


6. lfe Olorun ti ki ye

   Eje kristi iyebiye

   Ore-Ofe alainiwon

   Gbe gbogbo re ga n'nu mi. 

Egbe: An emi, an’emi...


7. Ma koja, mi dariji mi

   Fa mi mora, Oluwa

   “Gba o nf’ibukun f'elomi, 

   Masai f‘ibukun fun mi.

Egbe: An emi, an’emi 

      Ro ojo na sori mi. Amin

English »

Update Hymn