HYMN 266

S.124 t.H.C 336 11s (FE 286)
"Ikilo meta - Ma ba ja, ma bi ninu 
ma pa ina Emi" - 1 Tess. 5:191. lWO elese, Emi nfi anu pe 

   Okan re t‘o ti yigbi ninu ese 

   Ma se ba Emi ja, ma pe titi mo 

   Ebe Olorun re Ie pari loni.


2. Omo Ijoba, mas'eru ese mo; 

   Gb’ebun Emi Mimo ati itunu 

   Ma bi Emi ninu, Oluko re ni 

   K’a ba le se Olugbala re logo.


3. Tempili d'ibaje ewa re d‘ile

   lna pepe Olorun fere ku tan

   Bi a fi ife da, O si le tun ran 

   Mase pa ‘na Emi, Oluwa mbo wa. Amin

English »

Update Hymn