HYMN 269

H.C.157. 6s. 4s (FE 289) 
"Nitori oruko Re dari ese mi ji"
- Ps. 25:111. Ki se l‘aini reti 

   Ni mo to wa

   Ki se l’aini ‘gbagbo

   Ni mo kunle

   Ese ti gori mi 

   Eyi sa l‘ebe mi

   Eyi sa I'ebe mi, 

   Jesu ti ku.


2. A! ese mi poju

   O pon koko!

   Adale, adale

   Ni mo nd’ese!

   Ese niferan Re 

   Ese aigba O gbo, 

   Ese aigba O gbo 

   Ese nlanla!


3. Oluwa mo jewo 

   Ese nla mi

   O mo bi mo ti ri 

   Bi mo ti wa

   Jo we ese mi nu! 

   K‘okan mi mo Ioni 

   K’okan mi mo Ioni 

   Ki ndi mimo.


4. Olododo ni O, O ndariji 

   L’ ese agbelebu

   Ni mo wole

   Jek'eje iwenu

   Eje Odagutan, Eje Odagutan 

   We okan mi.


5. ‘Gbana, alafia

   Y‘o d’okan mi 

   ‘Gbana, ngo ba O rin,

   Ore airi 

   Em'o fara ti O

   Jo ma to mi s'ona

   Jo ma to mi s‘ona

   Titi aiye.  Amin

English »

Update Hymn