HYMN 275

C.M.S 148 t.H.C 94 S.M (FE 295)
"Wa eni mi" - Isa. 26:201. BABA wa orun npe 

   Krist‘ npe wa sodo Re 

   Ore wa pelu won o dun 

   Dapo wa y’o s’owon.


2. Olorun nkanu mi

   O dar‘ese mi ji 

   Olodumare s’okan mi 

   O f’ogbon to pa mi.


3. Ebun Re ti po to! 

   Ol'opo isura

   T’a t’owo Olugbala pin 

   Ti a f’eje Re ra!


4. Jesu, Ori ‘ye mi

   Mo fi ‘bukun fun O 

   Alagbawi lodo Baba 

   Asaju lodo Re.


5. Okan at’ife mi

   E duro je nihin

   Titi ‘dapo yio fi kun 

   L'oke orun l’ohun. Amin

English »

Update Hymn