HYMN 276

H.C 2nD eD.,106 or
t.H.C 552 L.M (FE 296)
"On yio joba lati okun de okun
 - Ps. 72:81. JESU yio joba ni gbogbo 

   lbit’a ba le ri orun 

   ‘Joba Re yo tan kakiri 

   ‘Joba Re ki y’o nipekun.


2. On l’ ao ma gbadura si, 

   Awon oba yio pe l’Oba 

   Oruko Re b‘orun didun

   Y’o ba ebo oro goke.


3. Gbogbo oniruru ede

   Y’o fi fe Re korin didun 

   Awon omode o jewo

   Pe, ‘bukun won t’odo Re wa.


4. ‘Bukun po nibit’On joba 

   A tu awon onde sile 

   Awon alare ri isimi 

   Alaini si ri ‘bukun gba.


5. O f'agbara iwosan han

   Iku, egun ko ni 'pa mo

   N'nu Re n'iran Adam nyangan

   'Won ri opo ibukun gba.


6. Ki gbogho eda k'o dide

   Ki nwon f‘ola fun Oba wa;

   K’Angel‘ tun wa t‘awon t’orin

   Ki gbogb' aiye jumo gberin. Amin

English »

Update Hymn