HYMN 278

C.M.S 156 T.H.C 182 C.M (FE 298)
"Pa oju Re mo kuro lara ese mi" 
- Ps. 51:91. RO iponju mi, Oluwa

   Ran iranlowo Re!

   Okan mi daku fun 'gbala

   Ise mi ki o pin?


2. Mo ri pe o dara fun mi

   Bi Baba mi na mi

   Iya mu mi k ofin Re 

   Ki ngeke mi le O.


3. Mo mo pe idajo Re to

   Bi o tile muna

   Iponju ti mo f'ori ti

   O ti odo Re wa.


4. K'emi to m'owo ina Re

   Emi a ma sina

   Sugbon bi mo ti k'oro Re

   Emi ko sako mo. Amin

English »

Update Hymn