HYMN 279
C.M. 40 t.H.C 266 L.M (FE 306)
"Bi enyin o ba gbo ohun re, e ma se
aiya yin le" - Ps. 95:7, 8
1.  MURA, elese, lati gbon 
     Ma duro de ojo ola
     Niwon b'o ti kegab ogbon
     Be l'o si soro lati ti.
2.  Murs lati bere anu
     Ma duro de ojo ola
     Ki igba re ko ma ba tan 
     Ki ojo ale yi to tan.
3.  Mura, elese k’pada 
     Ma duro de ojo ola 
     Nitorik’egan ma ba o 
     K’ojo ola k’o to bere.
4.  Mura lati gba ibukun 
     Ma duro de ojo ola 
     Ki fitila re ma ba ku 
     K’ise rere re to bere.
5.  Oluwa, y‘elese pada
     Ki kuro ninun were re
     Ma je k’o tapa s’imo Re 
     K’o ma f'egbe re se 'lora.  Amin
English »Update Hymn