HYMN 29

C.M.S. t.H.C. 68, S.M (FE 46) 
“Ranti ojo isimi lati Io o ni mimo"
- Eks 20:8


1. OLORUN wa own,
   
   T'o fi ojo mefa

   Da nkan ghogho ti mbe laiye, 

   Simi nijo keje.


2. O pase k‘a bowo 

   Fun ojo isimi, 

   lbunu Re tobi pupo 

   S‘awon t'o o rufin yi.


3. Awon baba nla wa

  Ti ku nin'okunkun; 

  Nwon je ogbo aborisa 

  Nwon ko mo ofin Re.


4. Awa de, Oluwa 

  Gege bi ase Re, 

  Lehin ise ijo mefa, 

  Lati se ife Re.


5. Mimo l’ojo oni,

   O ye ki a simi

   K’a pejo ninu ile Re 

   K’a gbo 'ro mimo Re.


6. lsimi nla kan ku 

   F'awon enia Re, 

   Om’Olorun, Alabukun 

   Mu wa de ‘simi re! Amin

English »

Update Hymn