HYMN 292

t.H.C. 233 C.M (FE 313) 
"lhinrere kristi agbara Olorun nmi
si igbala” - Rom. 1:161. KRIST t‘agbelebu l’orin wa, 

   ljinle t’awa nso

   O j’egan loju awon ju 

   Were lowo Griki.


2. Sugbon okan t'Olorun ko 

   F‘ayo gba oro na

   Nwon ri ogbon, ipa, ife 

   T’o han n’Oluwa won.


3. Adun, oruko Re yiye

   Mu soji s’okan won 

   Aigbagbo l’ohun t'o ba ni je 

   Si ebi at’iku.


4. Lai j'OIorun t‘o or‘ofe ka 

   Bi owara ojo

   Lasan l‘Apollos funrugbin 

   Paul si le gbin lasan. Amin

English »

Update Hymn