HYMN 294

(FE 315) HC 184 t. H.C 2nd
Ed 165 D. 8s 7s
"On a ru aisedede won" - Isa. 53:111. W‘OLORI Alufa Giga

   B'o ti gbe ebe wa lo 

   L‘ogba, o f 'ikedun wole 

   O f'eru dojubole 

   Angeli f’idamu duro 

   Lati ri Eleda be

   Awa o ha wa l’aigbogbe 

   T’a mo pe tori wa ni?


2. Kiki eje Jesu nikan

   L'ole yi oka pada

   On I‘o le gba wa n’nu ebi 

   On l’o le m’okan wa ro 

   Ofin at‘ikilo ko to

   Nwon ko si le nikan se 

   Ero yi l'o le m'okan ro 

   Oluwa ku dipo mi!


3. Jesu, gbogbo itunu wa 

   Lat‘odo Re l’o ti nwa

   lfe, ‘gbagbo, reti, suru 

   Gbogbo re I'eje Re ra 

   LAt’ inu ekun Re l'a ngba 

   A ko da ohun kan ni

   Lofe n’Iwo nfi won tore

   Fun awon t‘o s’ alaini. Amin

English »

Update Hymn