HYMN 297

H.C 183 t. 164 TABI 183 C.M 
(FE 318)
“W odo-agutan Olorun” - John 1:361. WO Odagutan ti o ru 

   E ru re Ior’igi

   O ku lati da igbekun 

   O t‘eje Re fun o.


2. W‘Olugbala, tit’ iran na 

   Y‘o fi fa okan re

   Fi omije rin ese Re

   Ma kuro lodo Re.


3. Wo, titi ife yio fi

   Joba lor’okan re 

   Tit‘agbara Re y’o fi han 

   Lor'ara on emi.


4. Wo, b’iwo ti nsare ije

   Ore re titi ni

   Y‘o pari ‘se Re t' O bere

   Or'ofe y'o j’ogo. Amin

English »

Update Hymn