HYMN 304

C.M.S 198. t.H.c. 190 C.M. (FE 345)
"Awan dwonyi ni not Odoaguatan 
Iehin nibikibi ti nre." - lfi. 14:41. E JE k’ a to Jesu wa lo, 

   Ni agbala nla ni;

   Nibiti O nlo gbadura, 

   Nibit' O nlo kanu.


2. K' a wo b’ O ti dojubole 

   T' o nmi imi edun;

   Eru ese wa l‘ O gberu, 

   Ese gbogbo aiye.


3. Elsese, wo Oluwa re, 

   Eni mimo julo; 

   Nitori re ni Baba ko, 

   Aiye si d‘ ota Re.


4. Iwo O ha wo laironu, 

   Lai k’ ese re silse? 

   Ojo idariji nkoja,

   Ojo igbala nlo. Amin

English »

Update Hymn