HYMN 306

C.M.S. 201 H.C. 483 C.M.
"Ni kaifari l a kon A mo 'gi"
- Luku 23:331. OKE Kan mbe jina rere,

   Lehin odi ilu,

   Nibit' a kan Oluwa mo,

   Eniti' O ku fun wa.


2. A ko lee mo, a ko le so,

   B'irora Re tito;

   Sugbon a mo pe n' tori wa,

   L'O se jiya nibe.


3. O ku kale huwa rere,

   K' a le ri 'dariji;

   K' a si le d'orun nikehin

   N' itoye eje Re.


4. Ko tun s' eni 're miran mo

   To le sanwo ese,

   On lo le silekun orun,

   K' O si gba wa sile.


5. A! b' ife Re ti sowon to,

   O ye ka feran Re;

   K' a si gbeekele eje Re,

   K' a si se ife Re. Amin
 

English »

Update Hymn