HYMN 31

C.M.S. 31, C.H 159, t.H.C (FE 48)
64 C.M.
“lnu mi dun nigbati nwon wi fun mi
pe E je ka Io si ile Oluwa” - PS. 122:1


1. BI mo ti yo lati gb'oro 

   Lenu awon ore, 

   Pe, ‘Ni Sion ni k'a pe si 

   K'a p'ojo mimo.


2. Mo f‘onata at‘ekun re 

   Ile t'a se loso

   lle t’a ko fun Olorun 

   Lati fi anu han.


3. S‘agala ile ayo na 

   Leya mimo si lo

   Omo Dafidi wa lor'ite 

   O nda ejo nibe.


4. O gbo iyin at‘igbe wa; 

   Bi ohun eru re,

   Ti nya elese sib‘egbe 

   A nyo ni ‘wariri.


5. K‘ ibukun pelu ibe na, 

   Ayo nigbakugba

   K‘a fi ore ati ore 

   F’awon ti nsin nibe.


6. Okan mi bebe fun Sion 

   Nigbati emi wa;

   Nibe n'ibatan at'ore 

   At'olugbala wa. Amin

English »

Update Hymn