HYMN 320

C.M.S 219 H.C 7s. 8s 4 (FE 343)
“Kiyesi i, emi mbe laye titi lai"
 - 1 Ifi. 1:181. JESU ye, titi aiye 

   Eru iku ko ba ni mo 

   Jesu ye: nitorina

   Isa oku ko n'ipa mo 

   Alleluya.


2. Jesu ye, lat‘ oni lo

   Iku je ona si iye

   Eyi y'o je ‘tunu wa 

   ‘Gbat‘ akoko iku ba de 

   Alleluya.


3. Jesu ye, fun wa l’O ku 

   Nje Tire ni a o ma se 

   A o f'okan funfun sin 

   A o f'ogo f‘Olugbala 

   Alleluya.


4. Jesu ye, eyi daju 

   lku at'ipa okunkun 

   Ki y‘o le ya ni kuro 

   Ninu ife nla ti jesu 

   Alleluya.


5. Jesu ye, gbogbo 'joba 

   L‘orun, li aiye di Tire 

   E je ki a ma tele

   Ki a le joba pelu Re 

   Alleluya. Amin

English »

Update Hymn