HYMN 323

H.C 207 11s (FE 346)
"Mo si ni omo‐isika prun apadi 
ati ti iku lowo” - lfi.1:181.  "KABO, ojo rere,"

l'ao ma wi titi

A sete ‘ku loni, 

orun di tiwa

‘Wo Oku d'alaye, 

Oba tit' aiye! 

Gbogb‘eda Re Jesu, 

ni nwon njuba Re.

Egbe:  Kabo, ojo rere, l'ao ma wi titi 

A sete ku loni, orun di ti wa.


2.  Eleda, Oluwa, Emi alaye 

Lat'orun l'oti bojuwo 

sina wa

Om'Olorun papa ni Wo 

tile se

K’ O ba le gba wa la,

O di enia.


Egbe:  Kabo, ojo rere...


3.  'Wo Oluwa iye, O wa to 

'ku wo 

Lati f'ipa Re han, O sun 

n‘iboji

Wa, Eni Oloto, si m‘oro 

Re se

Ojo keta Re de, jinde 

Oluwa!

Egbe:  Kabo, ojo rere...


4.  Tu igbekun sile, t' E su de l'ewon,

Awon t'o si subu, jo gbe

won dide

F'ojurere Re han: jek' aiye riran

Tun mu 'mole wa de

'Wo sa ni 'mole.

Egbe:  Kabo, ojo rere, l'ao ma wi titi 

A sete ku loni, orun di ti wa.  Amin

English »

Update Hymn