HYMN 328

(FE 351)
K. 160 5t.S 747 88.6.
Wo ti di igbekun ni igbekun le"
- Ps. 68:181. JESU t'o ku, k'o gb’aiye la 

   Jinde kuro ninu oku

   Nipa agbara re

   A da sile lowo iku

   O d'igbekun n'igbekun Io 

   O ye, k‘o ma ku mo.


2. Enyin om'OIorun, e wo 

   Olugbala ninu ogo

   O ti segun iku

   Ma banuje maberu mo 
 
   O nlo pese aiye fun nyin 

   Yio mu yin lo ‘Ie.


3. O f’oju anu at'ife

   Wo awon ti O ra pada 

   Awon ni ayo Re

   O ri ayo at‘ise won

   O bebe ki nwon le segun 

   Ki nwon ba joba lai. Amin

English »

Update Hymn