HYMN 344

(FE 367)
C.M.S 243 H.C 280 H.C 78 D 7s
"lwo ti goke si ibi giga" - Ps. 68:181. KRISTI, lehin isugun 

   lwo ti goke lo 

   Kerubu at’ogun-orun 

   Wa sin O goke lo 

   K'aiye so ‘tan na jade 

   Emmanueli wa

   Ti s‘ara iy’ara wa 

   G’or‘ite Baba.


2. Nibe l'O duro, t‘O nso 

   Agbara eje Re

   O mbebe fun elese 

   “Wo Alagbawi wa 

   Gbogbo ayidayida 

   T’ayo, t’aniyan wa, 

   N’lwo nse iyonu si 

   T'lwo si mbebe fun.


3. Nitori itoye nla

   Ti agbelebu Re

   K’O fi Emi Re fun wa 

   So ofo wa d’ere

   Titi nipa iyanu

   Okan wa o goke

   Lati ba O gbe titi

   Li ayo ailopin. Amin

English »

Update Hymn