HYMN 348

H.C 234 D.S.M (FE 371)
"Eni na ti o sokale li o si goke lo 
si ibi ti O ga ju gbogbo orun lo"
- Efe. 4:101.  lwo ti goke lo,

S’ile ayo orun 

Lojojumo yite re ka 

L‘a ngbo orin iyin 

Sugbon awa nduro 

Labe eru ese 

Jo ran Olutunu Re wa 

K’o si mu wa lo ‘le.


2.  lwo ti goke lo

Sugbon saju eyi,

O koja ‘rora kikoro

K'o to le de ade

Larin ibanuje

L'a o ma te siwaju

K‘ona wa t'o kun f'omije 

To wa si odo Re.


3.  Iwo ti goke lo

Iwo o tun pada

Awon egbe mimo l'oke 

Ni y’o ba O pada

Nipa agbara Re

K’awa k’a ku n’nu Re

Gbat'a ba ji l’ojo‘dajo 

Fi wa si otun Re.  Amin

English »

Update Hymn