HYMN 360

(FE 382)
C.M.S 418 t. H.C 585
"Ewe ati agba duro niwaju Olorun" 
- Ifi 20:12 
Tune: Baba mi gba mba Nsako lo1. A WA f ’ori bale/fun O Jesu

  ‘Wo ti s’Olori ljo awon/enia re, 

  ljo ti nibe laiye yi, a/ti lo/run 

  pelu Alleluya!


2. ‘Wo t‘o ku to si jin/de fun wa

   T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi 

   wa K’ogo at’olanla/je Tire

   Alleluya!


3. Ati li ojo nla Pen/tikosti

   Ti o ran Parakliti/si aiye 

  Olutunu nla re ti/mba wa 

  gbe; Alleluya!


4. Lat’ori ite Re lo/ke orun

   L’O si nwo gbogbo awon 

   o/jise Re T'o si nsike gbogbo 

   awon Aje/ riku Re. Alleluya!


5. A fi iyin at‘olanla f’o/oruko Re, 

   N'tori iku gbogbo awon o/jise Re,

   Ni gbogbo ile! A/gbaye yi 

   Alleluya! Amin

English »

Update Hymn