HYMN 362

CM (FE 384)

   

1. E GBO b‘awon Angeli ti 

   Nfi Ogo f'Olorun

   Ati awon Olus‘Agutan 

   Nfi ‘yin fun U,

2. Gbogbo ogun orun pelu 

   Agba mejila

   Kerubu pelu Serafu 

   Nfi ‘yin fun U.


3. Oke meje at'egbaji 

   Awon Agba woli

   Awon t’o nfe l’Olugbala 

   Nf ‘yin fun U.


4. Gbogbo’Ogun orun, e ho ye

   Aiye gbo iro na,

   Imisi Emi ba le wa 

   Awa nyin I.


5. N’torina awa Kerubu 

   Ati Serafu 

   Ninu aginju aiye yi 

   Nyin Baba.


6. Ogo fun Baba Olore 

   Ogo f’Omo Re

   Ogo ni fun Emi Mimo 

   Loke Orun. Amin

English »

Update Hymn