HYMN 377

(FE 398)
Tune: Jeka layo ninu Jesu1. EMl orun jare wa, 

   Wa gunwa s’okan wa 

   Ko se ‘le re ninu wa 

   Awa elese mbe O o.


2. Gbat’a wa n’ile aiye

   A kun f’opo asise

   T’o nfa danwo wa ba wa 

   Oluwa ye, jowo gba wa o.


3. Nigbati idanwo ba de 

   T'ara gbogbo le ko wa 

   Mura s'esin, ghadura 

   Jesu yio si wa gbe o Ieke.


4. Nihin l‘ore le tan o

   Pelu baba at‘iya

   Mura s'esin, p'Oluwa 

   ‘Gbayi ni iwo mo Jesu l‘ore.


5. T‘osan t‘oru I'Ongbo 

   Gbogbo imikanle re 

   Ki o to pe O gbo O 

   Bayi ni ileri re si O.


6. Pe mi loru ati osan

   Pelu emi igbagbo 

   Gb'okan s’oke s‘Oluwa 

   Jehovah Jire yio silekun.


7. F’lfe han k’o si ma se

   lse idariji niso 
 
   Mu'gbagbo pelu ‘se re 

   ‘Gbayi ni Jesu to gba o la. Amin

English »

Update Hymn