HYMN 378

(FE 399)
Tune: E ma te siwaju serafu mimo1. EMI orun sokale

   Wa gbe ‘nu ile yi

   Ati eda alaye merin t‘o ngbe 

   orun Sokale wa l'agbara nyin

   Lat‘ oke mimo

   Ki adua aiyeraiye le wa

   s'aiye wa,

   E wa josin, e wa josin

   ninu ile yi

   Ki gbogbo ‘dawole wa le 

   yori si rere.


2. Ki ase to sokale fun Baba nla wa,

   Solomon n’n adura re ni iyasimimo

   Ile Olorun aiyeraiye ti Jerusalemu

   Ni origun mererin to wa laiye yi

   Le wa dahun s'adura wa ninu ile yi 

   B'O ti dahun si Baba

   nla wa Solomon.


3. Baba orun, Olore, juba wa ninu ile yi

   Awa omo Re tun de wa bere lowo Re,

  Omo ko san, omi ‘ponju omi ko ri Re,

  Omi nfe 'bukun omi ko le yin O l’ogo

  Jowo fun wa, jowo fun wa ni ibere,

  K‘ adura wa ‘gbagbogbo le yori si idahun.


4. F’awon asiwaju l’ore-ofe kikun;

   B'O ti f'awon ti igbani l’aginju aiye yi 

   Nwon sise li oruko Re,

   nwon gb’ade ogo 

   F'awon na l’Emi Mimo lati gbade ogo; 

   Baba njiyin, iya njiyin, Aposteli nyin;

   Ati awon Efanjetist at’ Olus’agutan.


5. K’ibukun ore-ofe kari gbogbo ljo,

   Lati agba titi d'ewe ati awon Oloye;

   Mary, Martyr. Ayab’ Esther 

   Awon Oluranlowo iya at‘

   awon to tun mbo 

   Baba nla ati f'ogo Om‘ogun ‘gbala 

   Ki‘ bukun Olodumare 

   Wa lori akorin. Amin

English »

Update Hymn