HYMN 379

C.M.S 273 H.C 595 (FE 400)
"O mi i won, O ni e gba Emi Mimo”
- Job. 20:22 
Tune: Bi mo ti ri1. WA mi si wa, Emi Mimo 

   Tan ‘na orun si okan wa 

   Emi af’ororo yan ‘ni

   Ti f’emi meje re funni.


2. lse nla Re at‘oke wa 

   N‘itunu, iye, ina ife 

   F‘imole Re igbagbogbo 

   Le okunkun okan wa lo.


3. F'ororo ore-ofe Re 

   Pa oju eri wa ko dan

   L‘ota jina s'ibugbe wa 

   lre n’igbe ‘biti ‘Wo nso.


4. Ko wa k'a mo Baba, Omo

   Pelu Re l’okansoso

   Titi aiye ainipekun

   Ni k‘eyi ma je orin wa. Amin

English »

Update Hymn