HYMN 38

C.M.S. 37, H.C 222, L.M. (FE 55) 
“Nitori, Iwo Oluwa, Ii o ti mu mi
yo nipa ise Re" - Ps. 92:4


1. DlDUN n‘ise na, Oba mi 

   Lati ma yin Oruko Re; 

   Lati se ‘fe Re l'owuro 

   Lati so oro Re l'ale.


2. Didun l’ojo ‘simi mimo 

   Lala ko so fun mi loni 

   Okan mi ma korin iyin 

   Bi harpu Dafidi didun.


3. Okan mi o yo n'Oluwa 

   Y'o yin ise at’oro Re, 

   lse ore Re ti po to! 

   ljinle si ni imo Re.


4. Emi o yan ipo ola 

   Gb‘ore-ofe ba we mi nu 

   Ti ayo pupo si ba mi, 

   Ayo mimo lat' oke wa.


5. "Ghana, ngo ri, ngo gbo ngo mo, 

   Ohun gbogbo ti mo ti nfe 

   Gbogbo ipa mi y'o dalu

   Lati se ‘fe Re titi lai. Amin


English »

Update Hymn