HYMN 380

C.M.S 274. o.t.H.C 224, 7s (FE 401)
"On o si fun nyin Ii Olutunu miran ki o 
ma banyin gbe titi Iai" - John 14:161. EMl Mimo sokale 

   Ba wa gbe ni aiye yi 

   Fi ohun orun han ni

   Si ba ni sin Olorun.


2. Ese wa ni okan wa

   Ti a ko le fi sile 

   Agbara wa ko to se

   Bi “Wo ko ba pelu wa".


3. Awa nfe k’ese parun 

   L’okan ati l'ara wa 

   Wa, Emi Mimo, jo wa 

   Ko we gbogbo ese nu.


4. Olorun, 'Wo l'awa nfe

   Fi Emi Re na fun wa

   K'a le pa ofin Re mo 

   K’a si rin ni one Re. Amin

English »

Update Hymn