HYMN 381

t.H.C 254 L.M (FE 402)
"Ko mi ni wa, ati imo rere" - Ps. 119:661. ADABA orun sokale 

   Gbe wa lo l’apa iye Re

   Ki o si gbe a wa ga soke 

   Ju gbogbo ohun aiye lo.


2. Awa iba le ri ite 

   Olodumare Baba wa 

   Olugbala joko nibe

   O gunwa l’awo bi tiwa.


3. Egbe mimo duro yi ka

   lte Agbara wole fun 

   Olorun han ninu ara

   O si tan ogo yi won ka.


4. Oluwa, akoko wo ni

   Emi o de bugbe won wole

   T'emi o ma ba won wole

   Ki nma sin O, ki nma korin? Amin

English »

Update Hymn