HYMN 390

O. t. H.C 97 7s (FE 413)
“Ogo ni fun Olorun li oke orun"
- Luku 2:141. E fi ogo fun baba

   Nipa Eniti a wa

   O ngbo adura wa 

   O nf'eti si orin won.


2. E fi ego fun Omo

   Kristi, ‘Wo ni Oba wa 

   E wa e korin s‘oke 

   S'Odaguntan elese.


3. Ogo fun Emi Mimo

   Bi ojo Pentikosti

   Ru aiya awon ewe 

   F’orin mimo s'ete won.


4. Ogo ni l‘oke orun 

   Fun Eni Metalokan 

   Nitori ihin rere

   Ati ife Olorun. Amin

English »

Update Hymn